Wednesday 5 April 2017

Waec 2017 Yoruba (Obj and Theory) May/June Expo

YORUBA 


2a)
-[gb]:Konsonanti Akunyun Afafase-fete-pe
Asenupe

-[h]:Konsonanti Aikunyun Afitan-an na pe
Afunupe

-[k]:Konsonanti Aikunyun Afafase pe Asenupe

-[r]:Konsonanti Aikunyun Afafase pe Aferigipe
2b)

[gb]:Bi apeere, ninu oro bi -igbin,agbagba,gbo
[h]:Bi apeere ninu oro bi-ehoro,iho, ahon
[k]:Bi apeere ninu bi-akaara,oka,katakata
[r]:Bi apeere ninu oro bi-Irin,irina
==================

5ai)
Gbolohun alaye
5aii)
Gbolohun ibeere
5aiii)
Gbolohun ase
5aiv)
Gbolohun amo
5av)
Gbolohun alalaye
5bi)
Ti o ba ri tunde,bami pe
5bii)
-
5biii)
Kani mori Tunde ni,mi o ni wa
5biv)
Yala ko losi Ilorin,tabi kowa si Ogbomoso

5bv)
Kaka ki n losi ileewe, ma lo si oko mi
===================

4. i. ORO ORUKO ASEBEERE: Oro oruko
asebeere ni maa n fi ropo oro oruka miiran
nini gbolohun ibeere apeere: Ewo wlo.

ii. ORO ORUKO ASOYE: Oro oruko asoye maa
n see idiwon bi oro-oruko ti o tele we po ti
kan-npa ni ki a fi eyan kun awon kan nigba ti
awon kan je wofun.
Apeere: opolopo, ogunlogo

iii. ORO - ORUKO AFIHAN: Oro-Oruko afihan
ni a maa n seda eyan asafihan lati ara re.
Apeere: Iyen - Iwonyen
Eyi - Iwonyi

iv. ORO-ORUKO IBIKAN: EYi je oro-oruko ti a
maa n nlo 'ibo' tabi ibikan se ibeere fun.
Apeere: Ibadan,Oyo,ita abule

v. ORO-ORUKO IGBA: EYi ni oro-oruko ti o
maa n toka si igba akoko ti nikan sele. A le
fi igba wo se Ibeere fun un.
Wan lo ni ana
O gbera ni aaro
--------------------

No comments:

Post a Comment